Ẹ́kísódù 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Síbẹ̀, àwọn àlùfáà onídán ní Íjíbítì fi agbára òkùnkùn wọn ṣe ohun kan náà,+ ìyẹn sì mú kí ọkàn Fáráò túbọ̀ le, kò sì fetí sí wọn bí Jèhófà ṣe sọ.+
22 Síbẹ̀, àwọn àlùfáà onídán ní Íjíbítì fi agbára òkùnkùn wọn ṣe ohun kan náà,+ ìyẹn sì mú kí ọkàn Fáráò túbọ̀ le, kò sì fetí sí wọn bí Jèhófà ṣe sọ.+