Sáàmù 25:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mú mi mọ àwọn ọ̀nà rẹ, Jèhófà;+Kọ́ mi ní àwọn ipa ọ̀nà rẹ.+ Sáàmù 27:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ,+Darí mi ní ọ̀nà ìdúróṣinṣin nítorí àwọn ọ̀tá mi. Sáàmù 86:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.+ Èmi yóò máa rìn nínú òtítọ́ rẹ.+ Fún mi ní ọkàn tó pa pọ̀* kí n lè máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.+ Sáàmù 119:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Jèhófà,+ kọ́ mi kí n lè máa tè lé àwọn ìlànà rẹ,Màá sì tẹ̀ lé e délẹ̀délẹ̀.+ Àìsáyà 30:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Etí rẹ sì máa gbọ́ ọ̀rọ̀ kan lẹ́yìn rẹ pé, “Èyí ni ọ̀nà.+ Ẹ máa rìn nínú rẹ̀,” tó bá ṣẹlẹ̀ pé ẹ yà sí apá ọ̀tún tàbí tó bá ṣẹlẹ̀ pé ẹ yà sí apá òsì.+
11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.+ Èmi yóò máa rìn nínú òtítọ́ rẹ.+ Fún mi ní ọkàn tó pa pọ̀* kí n lè máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.+
21 Etí rẹ sì máa gbọ́ ọ̀rọ̀ kan lẹ́yìn rẹ pé, “Èyí ni ọ̀nà.+ Ẹ máa rìn nínú rẹ̀,” tó bá ṣẹlẹ̀ pé ẹ yà sí apá ọ̀tún tàbí tó bá ṣẹlẹ̀ pé ẹ yà sí apá òsì.+