Dáníẹ́lì 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run mi, mo jẹ́wọ́, mo sì sọ pé: “Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́, Ẹni ńlá, tó yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù, tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́, tó sì ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+ tí wọ́n sì ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+
4 Mo gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run mi, mo jẹ́wọ́, mo sì sọ pé: “Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́, Ẹni ńlá, tó yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù, tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́, tó sì ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+ tí wọ́n sì ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+