-
Ẹ́kísódù 2:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àlùfáà Mídíánì+ ní ọmọbìnrin méje, àwọn ọmọ yìí wá fa omi, wọ́n sì pọnmi kún àwọn ọpọ́n ìmumi kí wọ́n lè fún agbo ẹran bàbá wọn lómi.
-
-
Ẹ́kísódù 2:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Lẹ́yìn náà, Mósè gbà láti dúró lọ́dọ̀ ọkùnrin náà, ó sì fún Mósè ní Sípórà+ ọmọ rẹ̀ kó fi ṣe aya.
-