-
Léfítíkù 16:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 “Kí Áárónì wá wọnú àgọ́ ìpàdé, kó bọ́ ẹ̀wù tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe, èyí tó wọ̀ nígbà tó lọ sínú ibi mímọ́, kó sì kó wọn sílẹ̀ níbẹ̀.
-