Nọ́ńbà 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Inú ibi mímọ́ jù lọ ni kí o ti jẹ ẹ́.+ Gbogbo ọkùnrin ló lè jẹ ẹ́. Kó jẹ́ ohun mímọ́ fún ọ.+