-
Léfítíkù 4:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Kí àlùfáà tí ẹ fòróró yàn+ náà wá mú lára ẹ̀jẹ̀ akọ màlúù náà, kó sì gbé e wá sínú àgọ́ ìpàdé;
-
-
Léfítíkù 16:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 “Ní ti akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti ewúrẹ́ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, tó mú ẹ̀jẹ̀ wọn wá sínú ibi mímọ́ láti fi ṣe ètùtù, kí ó kó wọn lọ sí ẹ̀yìn ibùdó, kó fi iná sun+ awọ wọn, ẹran wọn àti ìgbẹ́ wọn.
-