Léfítíkù 6:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “‘Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ àlùfáà ni kó jẹ ẹ́.+ Ohun mímọ́ jù lọ+ ni. 30 Àmọ́, ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ti mú lára ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sínú àgọ́ ìpàdé láti ṣe ètùtù ní ibi mímọ́.+ Ṣe ni kí ẹ fi iná sun ún.
29 “‘Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ àlùfáà ni kó jẹ ẹ́.+ Ohun mímọ́ jù lọ+ ni. 30 Àmọ́, ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ti mú lára ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sínú àgọ́ ìpàdé láti ṣe ètùtù ní ibi mímọ́.+ Ṣe ni kí ẹ fi iná sun ún.