-
Léfítíkù 3:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 “‘Tí ohun tó mú wá bá jẹ́ ẹbọ ìrẹ́pọ̀,*+ tó sì jẹ́ látinú ọ̀wọ́ ẹran ló ti fẹ́ mú un wá, yálà akọ tàbí abo, ẹran tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá ni kó mú wá fún Jèhófà. 2 Kó gbé ọwọ́ lé orí ẹran tó mú wá, kí wọ́n pa á ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé; kí àwọn ọmọ Áárónì, àwọn àlùfáà, sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sí gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ.
-
-
Léfítíkù 5:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Kó wọ́n lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà sí ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ, àmọ́ kó ro ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ.+ Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.
-