Léfítíkù 19:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “‘Tí ẹ bá rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ sí Jèhófà,+ kí ẹ rú ẹbọ náà lọ́nà tí ẹ ó fi rí ìtẹ́wọ́gbà.+ 6 Kí ẹ jẹ ẹ́ ní ọjọ́ tí ẹ bá rúbọ àti ní ọjọ́ kejì, àmọ́ kí ẹ fi iná sun+ èyí tó bá ṣẹ́ kù di ọjọ́ kẹta.
5 “‘Tí ẹ bá rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ sí Jèhófà,+ kí ẹ rú ẹbọ náà lọ́nà tí ẹ ó fi rí ìtẹ́wọ́gbà.+ 6 Kí ẹ jẹ ẹ́ ní ọjọ́ tí ẹ bá rúbọ àti ní ọjọ́ kejì, àmọ́ kí ẹ fi iná sun+ èyí tó bá ṣẹ́ kù di ọjọ́ kẹta.