Ẹ́kísódù 22:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Kí ẹ fi hàn pé èèyàn mi tó jẹ́ mímọ́ ni yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹranko èyíkéyìí tí ẹranko búburú ti pa.+ Kí ẹ jù ú sí àwọn ajá. Léfítíkù 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Tí ẹnikẹ́ni* bá jẹ òkú ẹran tàbí èyí tí ẹran inú igbó fà ya,+ ì báà jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ tàbí àjèjì ló jẹ ẹ́, kó fọ aṣọ rẹ̀, kó fi omi wẹ̀, kó sì di aláìmọ́ títí di alẹ́;+ lẹ́yìn náà, á di mímọ́.
31 “Kí ẹ fi hàn pé èèyàn mi tó jẹ́ mímọ́ ni yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹranko èyíkéyìí tí ẹranko búburú ti pa.+ Kí ẹ jù ú sí àwọn ajá.
15 Tí ẹnikẹ́ni* bá jẹ òkú ẹran tàbí èyí tí ẹran inú igbó fà ya,+ ì báà jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ tàbí àjèjì ló jẹ ẹ́, kó fọ aṣọ rẹ̀, kó fi omi wẹ̀, kó sì di aláìmọ́ títí di alẹ́;+ lẹ́yìn náà, á di mímọ́.