Léfítíkù 19:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹ jẹ́ mímọ́, torí èmi Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.+ Nọ́ńbà 15:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Èyí á máa rán yín létí, ẹ ó sì máa pa gbogbo àṣẹ mi mọ́, ẹ ó sì wá jẹ́ mímọ́ lójú Ọlọ́run+ yín. 1 Pétérù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àmọ́ bíi ti Ẹni Mímọ́ tó pè yín, kí ẹ̀yin náà di mímọ́ nínú gbogbo ìwà yín,+
2 “Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹ jẹ́ mímọ́, torí èmi Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.+