Ẹ́kísódù 29:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí o wé láwàní náà sí i lórí, kí o sì fi àmì mímọ́ ti ìyàsímímọ́* sára láwàní náà;+ Ẹ́kísódù 39:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe aṣọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ẹni tó ń hun aṣọ ló ṣe é,+ 28 wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe láwàní+ àti aṣọ tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ tí wọ́n máa wé sórí,+ wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa ṣe àwọn ṣòkòtò péńpé,*+
27 Wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe aṣọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ẹni tó ń hun aṣọ ló ṣe é,+ 28 wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe láwàní+ àti aṣọ tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ tí wọ́n máa wé sórí,+ wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa ṣe àwọn ṣòkòtò péńpé,*+