- 
	                        
            
            Léfítíkù 8:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Lẹ́yìn náà, ó mú akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wá, Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì gbé ọwọ́ lé orí akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ náà. 15 Mósè pa á, ó fi ìka rẹ̀ mú ẹ̀jẹ̀ ẹran náà,+ ó fi sára àwọn ìwo tó wà ní gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ, ó sì wẹ ẹ̀ṣẹ̀ kúrò lára pẹpẹ náà, àmọ́ ó da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ, kó lè yà á sí mímọ́ láti ṣe ètùtù lórí rẹ̀. 
 
-