Léfítíkù 6:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àlùfáà tó fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ló máa jẹ ẹ́.+ Ibi mímọ́ ni kó ti jẹ ẹ́, nínú àgbàlá àgọ́ ìpàdé.+ Nọ́ńbà 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Inú ibi mímọ́ jù lọ ni kí o ti jẹ ẹ́.+ Gbogbo ọkùnrin ló lè jẹ ẹ́. Kó jẹ́ ohun mímọ́ fún ọ.+