Léfítíkù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “‘Tàbí tí ẹnì* kan bá fara kan ohun àìmọ́ èyíkéyìí, yálà òkú ẹran inú igbó tó jẹ́ aláìmọ́, ẹran ọ̀sìn tó jẹ́ aláìmọ́ tàbí ọ̀kan lára àwọn ohun alààyè tó ń gbá yìn-ìn tó jẹ́ aláìmọ́,+ ẹni náà máa di aláìmọ́, á sì jẹ̀bi, kódà tí kò bá tiẹ̀ mọ̀.
2 “‘Tàbí tí ẹnì* kan bá fara kan ohun àìmọ́ èyíkéyìí, yálà òkú ẹran inú igbó tó jẹ́ aláìmọ́, ẹran ọ̀sìn tó jẹ́ aláìmọ́ tàbí ọ̀kan lára àwọn ohun alààyè tó ń gbá yìn-ìn tó jẹ́ aláìmọ́,+ ẹni náà máa di aláìmọ́, á sì jẹ̀bi, kódà tí kò bá tiẹ̀ mọ̀.