21 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́jọ, nígbà tí àkókò tó láti dádọ̀dọ́ rẹ̀,+ wọ́n sọ ọ́ ní Jésù, orúkọ tí áńgẹ́lì náà pè é kí wọ́n tó lóyún rẹ̀.+
22 Bákan náà, nígbà tí àkókò tó láti wẹ̀ wọ́n mọ́ bó ṣe wà nínú Òfin Mósè,+ wọ́n gbé e wá sí Jerúsálẹ́mù, kí wọ́n lè fún Jèhófà,