Léfítíkù 12:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí obìnrin kan bá lóyún,* tó sì bímọ ọkùnrin, ọjọ́ méje ni kí obìnrin náà fi jẹ́ aláìmọ́, bó ṣe jẹ́ ní àwọn ọjọ́ ìdọ̀tí nígbà tó ń ṣe nǹkan oṣù.+ 3 Ní ọjọ́ kẹjọ, kí wọ́n dá adọ̀dọ́+ ọmọkùnrin náà.*
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí obìnrin kan bá lóyún,* tó sì bímọ ọkùnrin, ọjọ́ méje ni kí obìnrin náà fi jẹ́ aláìmọ́, bó ṣe jẹ́ ní àwọn ọjọ́ ìdọ̀tí nígbà tó ń ṣe nǹkan oṣù.+ 3 Ní ọjọ́ kẹjọ, kí wọ́n dá adọ̀dọ́+ ọmọkùnrin náà.*