-
Léfítíkù 13:50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 Kí àlùfáà yẹ àrùn náà wò, kó sì sé ohun tó ní àrùn náà mọ́lé fún ọjọ́ méje.+
-
-
Léfítíkù 14:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 kí àlùfáà jáde kúrò nínú ilé náà lọ sí ẹnu ọ̀nà rẹ̀, kó sì ti ilé náà pa fún ọjọ́ méje.+
-
-
Nọ́ńbà 12:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Torí náà, wọ́n sé Míríámù mọ́ ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ méje,+ àwọn èèyàn náà ò sì tú àgọ́ wọn ká títí Míríámù fi pa dà wọlé.
-