ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 13:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àmọ́ tí àbààwọ́n tó yọ sí awọ ara onítọ̀hún bá funfun, tó rí i pé kò jẹ wọnú kọjá awọ, tí irun ibẹ̀ kò sì tíì funfun, kí àlùfáà sé ẹni tó ní àrùn náà mọ́lé fún ọjọ́ méje.+

  • Léfítíkù 14:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 kí àlùfáà jáde kúrò nínú ilé náà lọ sí ẹnu ọ̀nà rẹ̀, kó sì ti ilé náà pa fún ọjọ́ méje.+

  • Nọ́ńbà 12:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Torí náà, wọ́n sé Míríámù mọ́ ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ méje,+ àwọn èèyàn náà ò sì tú àgọ́ wọn ká títí Míríámù fi pa dà wọlé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́