ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 13:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Tí àlùfáà bá ti rí egbò náà, kó kéde pé aláìmọ́+ ni ẹni náà. Egbò náà jẹ́ aláìmọ́. Ẹ̀tẹ̀ ni.+

  • Léfítíkù 13:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 kí àlùfáà yẹ̀ ẹ́ wò. Tí irun tó wà lójú àbààwọ́n náà bá ti funfun, tó sì rí i pé ó ti jẹ wọnú kọjá awọ, ẹ̀tẹ̀ ló yọ jáde lójú àpá yẹn, kí àlúfáà kéde pé ẹni náà jẹ́ aláìmọ́. Àrùn ẹ̀tẹ̀ ni.

  • Léfítíkù 13:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 kí àlùfáà yẹ àrùn náà wò.+ Tó bá rí i pé ó jẹ wọnú kọjá awọ, tí irun ibẹ̀ pọ́n fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́, tó sì fẹ́lẹ́, kí àlùfáà kéde pé aláìmọ́ ni ẹni náà; ó ti ní àrùn ní awọ orí rẹ̀ tàbí ní àgbọ̀n rẹ̀. Ẹ̀tẹ̀ ló mú un ní orí tàbí ní àgbọ̀n.

  • Léfítíkù 13:42
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Àmọ́ tí egbò tó pọ́n bá yọ síbi tó pá ní orí rẹ̀ tàbí níwájú orí rẹ̀, ẹ̀tẹ̀ ló yọ sí i lórí tàbí níwájú orí rẹ̀ yẹn.

  • Nọ́ńbà 12:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ìkùukùu wá kúrò lórí àgọ́ náà, wò ó! ẹ̀tẹ̀ tó funfun bíi yìnyín+ sì bo Míríámù. Ni Áárónì bá yíjú sọ́dọ̀ Míríámù, ó sì rí i pé ẹ̀tẹ̀+ ti bò ó.

  • Nọ́ńbà 12:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Jọ̀ọ́, má ṣe jẹ́ ká fi sílẹ̀ báyìí bí ẹni tó ti kú, tí ìdajì ara rẹ̀ ti jẹrà kí wọ́n tó bí i!”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́