Diutarónómì 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Tí àrùn ẹ̀tẹ̀* bá yọ, kí ẹ rí i pé ẹ ṣe gbogbo ohun tí àwọn àlùfáà tó jẹ́ ọmọ Léfì bá ní kí ẹ ṣe.+ Kí ẹ rí i pé ẹ ṣe ohun tí mo pa láṣẹ fún wọn gẹ́lẹ́. Málákì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó yẹ kí ìmọ̀ máa wà ní ètè àlùfáà, ó sì yẹ kí àwọn èèyàn máa wá òfin* ní ẹnu rẹ̀,+ torí ìránṣẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni.
8 “Tí àrùn ẹ̀tẹ̀* bá yọ, kí ẹ rí i pé ẹ ṣe gbogbo ohun tí àwọn àlùfáà tó jẹ́ ọmọ Léfì bá ní kí ẹ ṣe.+ Kí ẹ rí i pé ẹ ṣe ohun tí mo pa láṣẹ fún wọn gẹ́lẹ́.
7 Ó yẹ kí ìmọ̀ máa wà ní ètè àlùfáà, ó sì yẹ kí àwọn èèyàn máa wá òfin* ní ẹnu rẹ̀,+ torí ìránṣẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni.