-
Léfítíkù 13:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àmọ́ tí àbààwọ́n tó yọ sí awọ ara onítọ̀hún bá funfun, tó rí i pé kò jẹ wọnú kọjá awọ, tí irun ibẹ̀ kò sì tíì funfun, kí àlùfáà sé ẹni tó ní àrùn náà mọ́lé fún ọjọ́ méje.+
-