ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 13:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Tí nǹkan kan bá lé sí ara* ẹnì kan, tó sé èépá tàbí tí awọ ara rẹ̀ yọ àbààwọ́n, tó sì lè yọrí sí àrùn ẹ̀tẹ̀*+ ní awọ ara rẹ̀, kí wọ́n mú un wá sọ́dọ̀ àlùfáà Áárónì tàbí ọ̀kan lára àwọn ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà.+

  • Léfítíkù 13:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Tí àlùfáà bá ti rí egbò náà, kó kéde pé aláìmọ́+ ni ẹni náà. Egbò náà jẹ́ aláìmọ́. Ẹ̀tẹ̀ ni.+

  • Máàkù 1:44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 ó sọ fún un pé: “Rí i pé o ò sọ nǹkan kan fún ẹnikẹ́ni, àmọ́ lọ fi ara rẹ han àlùfáà, kí o sì mú àwọn ohun tí Mósè sọ dání láti wẹ̀ ọ́ mọ́,+ kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”+

  • Lúùkù 17:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nígbà tó rí wọn, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ fi ara yín han àwọn àlùfáà.”+ Bí wọ́n ṣe ń lọ, ara wọn mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́