ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 2:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Kí ohunkóhun tó bá ṣẹ́ kù lára ọrẹ ọkà náà jẹ́ ti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀,+ ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́+ látinú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.

  • Léfítíkù 7:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Òfin ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà kan ẹbọ ẹ̀bi; àlùfáà tó fi ṣe ètùtù ló ni ín.+

  • 1 Kọ́ríńtì 9:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé àwọn ọkùnrin tó ń ṣe iṣẹ́ mímọ́ máa ń jẹ àwọn nǹkan tẹ́ńpìlì àti pé àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nídìí pẹpẹ máa ń gba ìpín nídìí pẹpẹ?+

  • 1 Kọ́ríńtì 10:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ẹ wo Ísírẹ́lì lọ́nà ti ara: Ǹjẹ́ àwọn tó ń jẹ ohun tí a fi rúbọ kì í ṣe alájọpín pẹ̀lú pẹpẹ?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́