- 
	                        
            
            Léfítíkù 13:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        51 Tó bá yẹ àrùn náà wò ní ọjọ́ keje, tó sì rí i pé ó ti ràn lára aṣọ náà, lára òwú tó wà lóròó tàbí èyí tó wà ní ìbú tí wọ́n fi hun aṣọ náà tàbí lára awọ (láìka ohun tí wọ́n ń fi awọ náà ṣe), àrùn ẹ̀tẹ̀ tó le gan-an ni, aláìmọ́+ sì ni. 
 
-