-
Léfítíkù 13:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 kí àlùfáà yẹ àrùn náà wò.+ Tó bá rí i pé ó jẹ wọnú kọjá awọ, tí irun ibẹ̀ pọ́n fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́, tó sì fẹ́lẹ́, kí àlùfáà kéde pé aláìmọ́ ni ẹni náà; ó ti ní àrùn ní awọ orí rẹ̀ tàbí ní àgbọ̀n rẹ̀. Ẹ̀tẹ̀ ló mú un ní orí tàbí ní àgbọ̀n.
-