Mátíù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wò ó! obìnrin kan tí ìsun ẹ̀jẹ̀+ ti ń yọ lẹ́nu fún ọdún méjìlá (12) sún mọ́ ọn láti ẹ̀yìn, ó sì fọwọ́ kan wajawaja tó wà létí aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀,+ Lúùkù 8:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Obìnrin kan wà tó ti ní ìsun ẹ̀jẹ̀+ fún ọdún méjìlá (12), kò sì tíì rí ìwòsàn lọ́dọ̀ ẹnikẹ́ni.+
20 Wò ó! obìnrin kan tí ìsun ẹ̀jẹ̀+ ti ń yọ lẹ́nu fún ọdún méjìlá (12) sún mọ́ ọn láti ẹ̀yìn, ó sì fọwọ́ kan wajawaja tó wà létí aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀,+