Léfítíkù 23:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí ni Ọjọ́ Ètùtù.+ Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ pọ́n ara yín* lójú,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.
27 “Ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí ni Ọjọ́ Ètùtù.+ Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ pọ́n ara yín* lójú,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.