-
Léfítíkù 25:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Kí o wá fun ìwo kíkankíkan ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje; ní Ọjọ́ Ètùtù,+ kí o mú kí ìró ìwo náà dún ní gbogbo ilẹ̀ yín.