19 Ohun tí ẹ máa ṣe fún wọn nìyí kí wọ́n lè máa wà láàyè, kí wọ́n má sì kú torí pé wọ́n sún mọ́ àwọn ohun mímọ́ jù lọ.+ Kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wọlé, kí wọ́n yan iṣẹ́ kálukú àti ohun tó máa gbé fún un. 20 Wọn ò gbọ́dọ̀ wọlé wá wo àwọn ohun mímọ́, ì báà jẹ́ fírí, àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, wọ́n máa kú.”+