Àìsáyà 53:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n gún un+ torí àṣìṣe wa;+Wọ́n tẹ̀ ẹ́ rẹ́ torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+ Ó jìyà ká lè ní àlàáfíà,+A sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.+ 6 Gbogbo wa ti rìn gbéregbère bí àgùntàn,+Kálukú ti yíjú sí ọ̀nà tirẹ̀,Jèhófà sì ti mú kó ru ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo wa.+ 2 Kọ́ríńtì 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹni tí kò mọ ẹ̀ṣẹ̀+ ni ó sọ di ẹ̀ṣẹ̀* fún wa, kí a lè di olódodo lójú Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀.+
5 Wọ́n gún un+ torí àṣìṣe wa;+Wọ́n tẹ̀ ẹ́ rẹ́ torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+ Ó jìyà ká lè ní àlàáfíà,+A sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.+ 6 Gbogbo wa ti rìn gbéregbère bí àgùntàn,+Kálukú ti yíjú sí ọ̀nà tirẹ̀,Jèhófà sì ti mú kó ru ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo wa.+