Léfítíkù 8:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹ ò gbọ́dọ̀ jáde ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé fún ọjọ́ méje, títí ọjọ́ tí wọ́n á fa iṣẹ́ lé yín lọ́wọ́ yóò fi pé, torí ọjọ́ méje ló máa gbà láti sọ yín di àlùfáà.*+
33 Ẹ ò gbọ́dọ̀ jáde ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé fún ọjọ́ méje, títí ọjọ́ tí wọ́n á fa iṣẹ́ lé yín lọ́wọ́ yóò fi pé, torí ọjọ́ méje ló máa gbà láti sọ yín di àlùfáà.*+