-
Léfítíkù 17:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 “‘Tí ọkùnrin kankan ní ilé Ísírẹ́lì tàbí tí àjèjì kankan tó ń gbé láàárín yín bá jẹ ẹ̀jẹ̀+ èyíkéyìí, ó dájú pé mi ò ní fi ojú rere wo ẹni* tó ń jẹ ẹ̀jẹ̀, èmi yóò sì pa á, kí n lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀. 11 Torí inú ẹ̀jẹ̀+ ni ẹ̀mí* ẹran wà, èmi fúnra mi sì ti fi sórí pẹpẹ+ fún yín kí ẹ lè ṣe ètùtù fún ara yín,* torí ẹ̀jẹ̀ ló ń ṣe ètùtù+ nípasẹ̀ ẹ̀mí* tó wà nínú rẹ̀.
-