Ẹ́kísódù 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.+ Ẹ́kísódù 20:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run fàdákà láti máa sìn wọ́n pẹ̀lú mi, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run wúrà fún ara yín.+ Diutarónómì 27:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gbẹ́ ère+ tàbí tó ṣe ère onírin,*+ tó jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+ iṣẹ́ ọwọ́ oníṣẹ́ ọnà,* tó sì gbé e pa mọ́.’ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’*)
4 “O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.+
23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run fàdákà láti máa sìn wọ́n pẹ̀lú mi, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run wúrà fún ara yín.+
15 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gbẹ́ ère+ tàbí tó ṣe ère onírin,*+ tó jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+ iṣẹ́ ọwọ́ oníṣẹ́ ọnà,* tó sì gbé e pa mọ́.’ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’*)