Ẹ́kísódù 34:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “O ò gbọ́dọ̀ fi irin rọ àwọn ọlọ́run.+ Léfítíkù 19:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ má ṣe yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí+ tàbí kí ẹ fi irin rọ àwọn ọlọ́run+ fún ara yín. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.
4 Ẹ má ṣe yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí+ tàbí kí ẹ fi irin rọ àwọn ọlọ́run+ fún ara yín. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.