-
Léfítíkù 18:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá arábìnrin rẹ lò pọ̀, ì báà jẹ́ ọmọ bàbá rẹ tàbí ọmọ ìyá rẹ, ì báà jẹ́ agbo ilé kan náà ni wọ́n bí yín sí tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́.+
-
-
Diutarónómì 27:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá bá arábìnrin rẹ̀ sùn, ì báà jẹ́ ọmọ bàbá rẹ̀ tàbí ọmọ ìyá rẹ̀.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)
-