ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 19:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+

  • Ẹ́kísódù 33:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Báwo ni àwọn èèyàn yóò ṣe mọ̀ pé èmi àti àwọn èèyàn rẹ ti rí ojúure rẹ? Ṣebí tí o bá bá wa lọ ni,+ kí èmi àti àwọn èèyàn rẹ lè yàtọ̀ sí gbogbo èèyàn yòókù tó wà ní ayé?”+

  • 1 Àwọn Ọba 8:53
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 53 Nítorí o ti yà wọ́n sọ́tọ̀ láti jẹ́ ogún rẹ nínú gbogbo aráyé,+ bí o ṣe gba ẹnu Mósè ìránṣẹ́ rẹ sọ̀rọ̀, nígbà tí ò ń mú àwọn baba ńlá wa jáde kúrò ní Íjíbítì, ìwọ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ.”

  • 1 Pétérù 2:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àmọ́ ẹ̀yin ni “àwọn èèyàn tí Ọlọ́run yàn, ẹgbẹ́ àlùfáà aládé, orílẹ̀-èdè mímọ́,+ àwùjọ àwọn èèyàn tó jẹ́ ohun ìní pàtàkì,+ kí ẹ lè kéde káàkiri àwọn ọlá ńlá”*+ Ẹni tó pè yín jáde kúrò nínú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀ àgbàyanu rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́