ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 28:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Kí o ṣe aṣọ mímọ́ fún Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, kó lè ní ògo àti ẹwà.+

  • Ẹ́kísódù 29:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 “Àwọn aṣọ mímọ́+ tó jẹ́ ti Áárónì ni àwọn ọmọ rẹ̀ yóò máa lò+ tí wọ́n bá ti fòróró yàn wọ́n, tí wọ́n sì di àlùfáà.

  • Léfítíkù 16:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 “Kí àlùfáà tí ẹ fòróró yàn,+ tí ẹ fiṣẹ́ lé lọ́wọ́* láti ṣe àlùfáà+ dípò bàbá rẹ̀+ ṣe ètùtù, kó sì wọ aṣọ ọ̀gbọ̀,+ aṣọ mímọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́