-
Nọ́ńbà 6:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ì báà jẹ́ bàbá rẹ̀, ìyá rẹ̀, arákùnrin rẹ̀ tàbí arábìnrin rẹ̀ ló kú, kò gbọ́dọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́,+ torí àmì wà ní orí rẹ̀ pé ó jẹ́ Násírì fún Ọlọ́run rẹ̀.
-
-
Nọ́ńbà 19:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “‘Òfin tí ẹ máa tẹ̀ lé nìyí tí ẹnì kan bá kú sínú àgọ́: Ẹnikẹ́ni tó bá wọnú àgọ́ náà àti ẹnikẹ́ni tó ti wà nínú àgọ́ náà tẹ́lẹ̀ máa jẹ́ aláìmọ́ fún ọjọ́ méje.
-