Àìsáyà 58:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ fún ẹni tí ebi ń pa lára oúnjẹ yín,+Kí ẹ mú aláìní àti ẹni tí kò rílé gbé wá sínú ilé yín,Kí ẹ fi aṣọ bo ẹni tó wà ní ìhòòhò tí ẹ bá rí i,+Kí ẹ má sì kẹ̀yìn sí àwọn èèyàn yín.
7 Ẹ fún ẹni tí ebi ń pa lára oúnjẹ yín,+Kí ẹ mú aláìní àti ẹni tí kò rílé gbé wá sínú ilé yín,Kí ẹ fi aṣọ bo ẹni tó wà ní ìhòòhò tí ẹ bá rí i,+Kí ẹ má sì kẹ̀yìn sí àwọn èèyàn yín.