Sáàmù 41:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Aláyọ̀ ni ẹni tó bá ń ro ti àwọn aláìní;+Jèhófà yóò gbà á sílẹ̀ ní ọjọ́ àjálù. Sáàmù 112:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ti pín nǹkan fún àwọn èèyàn káàkiri;* ó ti fún àwọn aláìní.+ צ [Sádì] Òdodo rẹ̀ wà títí láé.+ ק [Kófì] A ó gbé agbára* rẹ̀ ga nínú ògo. Òwe 19:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹni tó ń ṣojúure sí aláìní, Jèhófà ló ń yá ní nǹkan,+Á sì san án* pa dà fún un nítorí ohun tó ṣe.+ Òwe 22:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ọ̀làwọ́* yóò gba ìbùkún,Nítorí ó ń fún aláìní lára oúnjẹ rẹ̀.+
9 Ó ti pín nǹkan fún àwọn èèyàn káàkiri;* ó ti fún àwọn aláìní.+ צ [Sádì] Òdodo rẹ̀ wà títí láé.+ ק [Kófì] A ó gbé agbára* rẹ̀ ga nínú ògo.
17 Ẹni tó ń ṣojúure sí aláìní, Jèhófà ló ń yá ní nǹkan,+Á sì san án* pa dà fún un nítorí ohun tó ṣe.+