Ẹ́kísódù 25:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “Kí o tún fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe tábìlì,+ kí gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, kí fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, kí gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+ 24 Kí o fi ògidì wúrà bò ó, kí o sì ṣe ìgbátí wúrà sí i* yí ká. 1 Àwọn Ọba 7:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Sólómọ́nì ṣe gbogbo nǹkan èlò ilé Jèhófà, àwọn ni: pẹpẹ+ wúrà; tábìlì wúrà+ tí wọ́n á máa kó búrẹ́dì àfihàn sí;
23 “Kí o tún fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe tábìlì,+ kí gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, kí fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, kí gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+ 24 Kí o fi ògidì wúrà bò ó, kí o sì ṣe ìgbátí wúrà sí i* yí ká.
48 Sólómọ́nì ṣe gbogbo nǹkan èlò ilé Jèhófà, àwọn ni: pẹpẹ+ wúrà; tábìlì wúrà+ tí wọ́n á máa kó búrẹ́dì àfihàn sí;