-
Léfítíkù 27:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ní ọdún Júbílì, ilẹ̀ náà yóò pa dà di ti ẹni tó tà á fún un, yóò di ti ẹni tó ni ilẹ̀ náà.+
-
-
Nọ́ńbà 36:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Tí àkókò Júbílì+ bá wá tó fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ogún àwọn obìnrin náà máa kún ti ogún ẹ̀yà tí wọ́n máa fẹ́ wọn sí, ogún wọn ò sì ní sí lára ogún ẹ̀yà àwọn bàbá wa mọ́.”
-
-
Diutarónómì 15:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Ní òpin ọdún méje-méje, kí o máa ṣe ìtúsílẹ̀.+
-