50 Kí òun àti ẹni tó rà á ṣírò iye ọdún tó jẹ́ láti ọdún tó ti ta ara rẹ̀ fún un títí di ọdún Júbílì,+ kí owó tó sì ta ara rẹ̀ ṣe rẹ́gí pẹ̀lú iye ọdún náà.+ Bí wọ́n ṣe ń ṣírò owó alágbàṣe+ ni wọ́n á ṣe ṣírò owó rẹ̀ láwọn ọjọ́ tó fi ṣiṣẹ́ ní àkókò yẹn.