ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 4:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Kí àlùfáà fi ìka rẹ̀ mú lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà, kó fi sára àwọn ìwo+ pẹpẹ ẹbọ sísun, kó sì da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ ẹbọ sísun.+

  • Léfítíkù 8:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Mósè pa á, ó fi ìka rẹ̀ mú ẹ̀jẹ̀ ẹran náà,+ ó fi sára àwọn ìwo tó wà ní gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ, ó sì wẹ ẹ̀ṣẹ̀ kúrò lára pẹpẹ náà, àmọ́ ó da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ, kó lè yà á sí mímọ́ láti ṣe ètùtù lórí rẹ̀.

  • Léfítíkù 9:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Áárónì sún mọ́ pẹpẹ, ó sì pa ọmọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tó jẹ́ tirẹ̀.+ 9 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Áárónì gbé ẹ̀jẹ̀+ ẹran náà wá fún un, ó ki ìka rẹ̀ bọ ẹ̀jẹ̀ náà, ó sì fi sára àwọn ìwo pẹpẹ, ó wá da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ.+

  • Hébérù 9:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Àní bí Òfin ṣe sọ, ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo nǹkan ni wọ́n ń fi ẹ̀jẹ̀ wẹ̀ mọ́,+ ìdáríjì kankan ò sì lè wáyé àfi tí a bá tú ẹ̀jẹ̀ jáde.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́