Sáàmù 67:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ilẹ̀ yóò mú èso jáde;+Ọlọ́run, àní Ọlọ́run wa, yóò bù kún wa.+ Sáàmù 85:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bẹ́ẹ̀ ni, Jèhófà yóò pèsè ohun rere,*+Ilẹ̀ wa yóò sì máa mú èso jáde.+