-
Ìsíkíẹ́lì 36:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ẹ ó wá rántí àwọn ìwà búburú yín àti àwọn ohun tí kò dáa tí ẹ ṣe, ẹ ó sì kórìíra ara yín torí pé ẹ jẹ̀bi àti torí ìwà ìríra yín.+
-