-
Léfítíkù 13:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Kí àlùfáà yẹ àrùn tó yọ sí ẹni náà lára wò. Tí irun tó wà níbi tí àrùn náà yọ sí bá ti funfun, tó sì rí i pé àrùn náà ti jẹ wọnú kọjá awọ, àrùn ẹ̀tẹ̀ ni. Kí àlùfáà yẹ̀ ẹ́ wò, kó sì kéde pé ẹni náà jẹ́ aláìmọ́.
-
-
Léfítíkù 15:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ohun tó ń dà jáde lára rẹ̀ ti sọ ọ́ di aláìmọ́, yálà ó ṣì ń dà látinú ẹ̀yà ìbímọ rẹ̀ tàbí ibẹ̀ ti dí, aláìmọ́ ṣì ni.
-