Diutarónómì 4:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Torí Ọlọ́run aláàánú ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ.+ Kò ní pa ọ́ tì, kò ní pa ọ́ run, kò sì ní gbàgbé májẹ̀mú tó bá àwọn baba ńlá rẹ dá.+ 2 Àwọn Ọba 13:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́, Jèhófà ṣíjú àánú wò wọ́n, ó ṣojú rere sí wọn,+ ó sì bójú tó wọn nítorí májẹ̀mú rẹ̀ pẹ̀lú Ábúráhámù,+ Ísákì+ àti Jékọ́bù.+ Kò fẹ́ pa wọ́n run, kò sì ta wọ́n nù kúrò níwájú rẹ̀ títí di òní yìí. Nehemáyà 9:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nínú àánú ńlá rẹ, o ò pa wọ́n run,+ o ò sì fi wọ́n sílẹ̀, nítorí Ọlọ́run tó ń gba tẹni rò* àti aláàánú ni ọ́.+
31 Torí Ọlọ́run aláàánú ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ.+ Kò ní pa ọ́ tì, kò ní pa ọ́ run, kò sì ní gbàgbé májẹ̀mú tó bá àwọn baba ńlá rẹ dá.+
23 Àmọ́, Jèhófà ṣíjú àánú wò wọ́n, ó ṣojú rere sí wọn,+ ó sì bójú tó wọn nítorí májẹ̀mú rẹ̀ pẹ̀lú Ábúráhámù,+ Ísákì+ àti Jékọ́bù.+ Kò fẹ́ pa wọ́n run, kò sì ta wọ́n nù kúrò níwájú rẹ̀ títí di òní yìí.
31 Nínú àánú ńlá rẹ, o ò pa wọ́n run,+ o ò sì fi wọ́n sílẹ̀, nítorí Ọlọ́run tó ń gba tẹni rò* àti aláàánú ni ọ́.+